DOWNLOAD NEW MUSIC: Tohworship – Igunwa

DOWNLOAD NEW MUSIC: Tohworship – Igunwa

Arowosegbe Tosin popularly known as Tohworship is a praise/worship leader.

He was born on the 20th of January. He started music at his early age, He’s passionate about spreading the gospel of Jesus Christ through is song.

His song titled IGUNWA describes how great God seats as a King and resides in heaven.

It’s also a song of praise and worship to God almighty.

DOWNLOAD MUSIC HERE

 

Connect:

Facebook: Arowosegbe Tosin Tohworship

Instagram: iam_tohworship

Lyrics of Igunwa by Tohworship

Olorun to wo itanna ogo ni aso
Iwo lo pa kaja ogo si eji ka
Alaafin Orun

Chr: O ta sanmo gbororogbo
O fi Inu Orun see ibi igunwa

 1. Igunwa wa re o kun fun wura
  Igunwa wa re kun fun ogo tenikan Kan o le sakawe o
  Igunwa re o kun fun ewa to koja ogbon Ori eniyan
  O fi Inu Orun see ibi igun wa

Igunwa re, lagba merinlelogun pejo so
Igunwa re, ni iseda merin gbe kale
Igunwa re, ni it’s funfun gbe was
O fi Inu Orun see ibi igunwa.

Igunwa re, osumare nla gbe yo
Igunwa re, lesin funfun Kan fogo Yan togotogo
Igunwa wa, legbe gbe run ogun Orun gbe wa
O fi Inu Orun see ibi igunwa.

Chrs……

 1. Laye bi, oba ba Lori ibi to ni ipile si
  Sugbon no Orun, gbogbo re lo be no ikawo re nikan also
  Olorun Toni Orun, Toni Orun, Toni Orun
  O fi Inu Orun see ibi igunwa

O to Joba tele koto Joba
Are nla tenikan o mo ibi to to se wa o
Olopa Ogo, Alade ogo Oni irukere ogo
O fi Inu Orun see ibi igunwa

Ijinle lo je, ko seni to le to
To idi re
Araba ribiti, Aribi rabata o
Isaaju Orun, Isaaju aye bi
O fi Inu Orun see ibi igunwa.

Egbe Ori yin soke
Eyin enu ona gbogbo
Kajumo gbe yin soke
Eyin ilekun Ayeraye

Ki oba ogo ma Joba lo
Olorun Toni igunwa lorun
Ma da kojokojo Lori ite, alaafin Orun
Oba ogo majoba lo, ma Joba lo, ma Joba lo, ma Joba lo.

Baye ba nje aye
Borun si nje Orun, wa ma Joba lo, sa ma Joba lo

Call: Iwo to to Joba ki latetekose to fohun
Resp: Wa ma Joba lo
Call:Nigbati a ba Kaye kuro wa ma Joba lo
Resp: Wa ma Joba lo
Call: Gbongi ninu Orun, to ni ikawo Orun
Call:Asiri to gbe aye ro, Iwo lo mo o
Call: Olodu omo are, Iwo nikan ni
Call:Ato fise ogun ran, baba daadaa
Call: Edidi to mbe ninu meta ni okan also
Call: Ari Orun, Ari aye lekan soso

Do you love this post? Kindly comment on it now