DOWNLOAD Tope Alabi – You Are Worthy (Mp3, Video and Lyrics).
Here is a song titled“You Are Worthy by Tope AlabiTope Alabi from her album “Yes and Amen” which followed up her 2014 EP Oruko Run Tun
DOWNLOAD MUSIC HERE
LYRICS:
Hmmmmm
Ohhhhh
Ehhhhhhh
[Chorus X2]
You are worthy
you are worthy
you are worthy of my praise
Eleburuike oooo,
Oranmonisefayati oooo
aranibanilo ooooo
you are worthy
Oba to gba mi la o
olowo ina oooo
Iwo nikan logo ye ooo
you are worthy
[Chorus]
You are worthy
you are worthy
you are worthy of myppraise
Lion of the tribe of Judea
kinging in his majesty,
Ruler of the universe,
I tremble at your feet
Lion of the tribe of Judea
kinging in his majesty,
Ruler of the universe,
I tremble at your feet
Worthy of our worship
[Chorus x2]
You are worthy
you are worthy
you are worthy of my praise
Olola to ga ju lo
oloro to poju lo
ologo to ga ju
you are worthy
Oba to ju gbogbo oba lo
Ijoba ni bi gbogbo olori aye
isale ile alainipekun ni o
[Chorus x2]
You are worthy
you are worthy
you are worthy of my praise
Oforun nikan se kiki da wura
Oda orun pelu aye pelu ara oto
ebo mi Aji to la
mo gbo su ba fogo ra Bale
ibeere ogo arin ogo olunkangun Igbeyin ogo
eniti gbogbo aye yio
Pada wa bo
Kabiesi oooo
araye koba ni kabiesi
won ni kade pe lori ki
Bata pe lese o
iwo nikan ni kabiesi ta o gbodo so pe kade pe lori fun
Ewo a o gbodo ni ki bata pe lese lailai sade ta o
Mo gba to gori e se bata ta o mo gba to wo ese re