Elvee Abiodun - Gbadura artwork

Elvee Abiodun – Gbadura

Elvee Abiodun - Gbadura artwork
Elvee Abiodun – Gbadura

Elvee Abiodun – Gbadura

Download – Gbadura by Elvee Abiodun

Elvee Abiodun, is a Gospel Music songwriter, composer, and musician into gospel pop and cool high life song.

With an incredible appetite for God, and for life. Elvee Abiodun.

Is passionate about showing the world what is possible with God by glorifying Jesus the Christ through ministering music. His inspired by the Holy spirit and artists like Moore, Nathaniel Bassey, Dunsin Oyekan, Adeyinka Alaseyori,Travis Greene, Sinach, amongst others.

DOWNLOAD MUSIC HERE

 

 

Elvee Abiodun – Gbadura LYRICS

Chorus
Ti oba le gbadura,
Iwo ari iyanu.
Ti oba le gbadura,
O re adayo.
Ti oba le gbadura,
Iwo ari iyanu.
Ti oba le gbadura
O re adayo.

Ti oba le gbadura,
Iwo ari iyanu.
Ti oba le gbadura,
O re adayo,
Ti oba le gbadura,
Iwo ari iyanu.
Ti oba le gbadura
O re adayo.

Daniel gbadura nse lori iyanu,
Jabesi gbadura nse lori iyanu,
Peteru gbadura nse lori iyanu,
Hezekiah gbadura nse lori iyanu,
Joshua gbadura nse lori iyanu,
Elijah gbadura nse lori iyanu,
Bi o ba le gbadura wa bori ogun,
Bi o ba le gbadura wa bori isoro.

Maria gbadura nse lobi iyanu,
Sarah gbadura nse lobi iyanu,
Elizabeth gbadura nse lobi iyanu,
Hannah gbadura nse lobi iyanu,
Rachael gbadura nse lobi iyanu,
Brother mi gbadura kole bi iyanu,
Sister mi gbadura kole bi iyanu,
Iyanu asele ti oba le gbadura.

Ti oba le gbadura,
Iwo ari iyanu.
Ti oba le gbadura,
O re adayo.
Ti oba le gbadura,
Iwo ari iyanu.
Ti oba le gbadura
O re adayo.

Ti oba le gbadura,
Iwo ari iyanu.
Ti oba le gbadura,
O re adayo.
Ti oba le gbadura,
Iwo ari iyanu.
Ti oba le gbadura
O re adayo.

Baba gbadura koleri batise,
Mama gbadura kole rona gbegba,
Brother gbadura ko deni nla,
Sister gbadura kole tayo laiye,
E jeka ka gbadura kale deni nla,
Awon to gbadura lo tayo laiye,
Adura gbigba olere pupo,
Adura gbigba lo fani soke laiyeee.

Ti oba le gbadura,
Iwo ari iyanu.
Ti oba le gbadura,
O re adayo.
Ti oba le gbadura,
Iwo ari iyanu.
Ti oba le gbadura
O re adayo.

Ti oba le gbadura,
Iwo ari iyanu.
Ti oba le gbadura,
O re adayo.
Ti oba le gbadura,
Iwo ari iyanu
Ti oba le gbadura
O re adayo.

Ti oba le gbadura,
Iwo ari iyanu.
Ti oba le gbadura,
O re adayo.
Ti oba le gbadura,
Iwo ari iyanu.
Ti oba le gbadura
O re adayo.

Do you love this post? Kindly comment on it now